Oriki – Olowu ‘Kangunere’

OLOWU KANGUNERE – A Profile:

Olowu-long

Oriki Kabiyesi

OBA (DR) OLUSANYA ADEGBOYEGA DOSUNMU

Adigun digun ba nini lara ja

A f’iwo f’iwo gb’alabosi subu

Suu su niwo Oko Iyabode

Olusanya, Isola erin, Omo a f’imo sekun

A f’imo Olua sete alaroka

Omo Omotunde, baba Moradeun

Ola mbolarin

Se b’oluwa ni n’sola gidi

Olusanya Ishola oko Olatunbosun

Baba Okelana, omo Okelana

Okelana omo Dosunmu, a gbo buruku di kaka raka

Omo Adekunle, omo Adetaloye, omo Isiade Amororo

Isiade Olubori agogo ‘kurin

0 lo biiri o f’ija gunle

o wo’se elomii, di d’ise tire mu

Aro ni l’ara bi oun eni

Jamolu Oyinbo, alopo l’ere

Aritun oba, ari p’onilu

Omo Asado ogan

Ojakara tan, o f’owo nu t’eko aso

Omo Oba nile loko

Omo somo tan peregede

Omo elomiran iba s’omo, ko l’awo omo l’ara OmoAmororo, Omo Agunloye bi Oyinbo

Lawunmi are Ilugun gbooro,

Omo Sorinlu sotike

Agbori esin na’ja, Ejire iyawo, a dara l’ewu roki ni’jo

Omo aperan nla b’ade

olowu-long2Olubori, oda o pagogo

Dosunmu, olode aadaro

A fi joojumo re sobi agbe

O l’esin ni madu madu

A b’iru esin dugbe dugbe

O so baba mesin lorun

Esin njeko, eniyan n jeun

Aja n mi peke peke

Dosunmu, alase ororun oko Olusuntan

A gbo buruku di kaka mora

Dosunmu, a to fara ti bi oke

Otiti f’ara ti

Oba ni Dosunmu, Oba l’Amororo

Agunloye bi Oyinbo, etc.

9 comments on “Oriki – Olowu ‘Kangunere’

  1. I came on this site because am interested in the oriki of owu… my husband is an orile owu citizen, comimng up to his birthday.. can someone help me please

    Like

    • 4 ur next ocassion if u need someone dat can chant u can call dis.dis number 08075416068 07080455002 azeez ajobiewe son or. Meet me on facebook AJOBIEWE JUNIOR

      Like

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s